Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 28:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn pẹlu awọn agbàgba pejọ, ti nwọn si gbìmọ, nwọn fi ọ̀pọ owo fun awọn ọmọ-ogun na
Pín
Mat 28YBCVMat 28:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì pe ìpàdé àwọn àgbàgbà Júù. Wọ́n sì fohùn ṣọ̀kan láti fi owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀ fún àwọn olùṣọ́.
Pín
Mat 28BMYOMat 28:12YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí àwọn olórí alufaa ti forí-korí pẹlu àwọn àgbà, wọ́n wá owó tí ó jọjú fún àwọn ọmọ-ogun náà.
Pín
Mat 28YCE