Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 27:60YBCV(Bibeli Mimọ)
O si tẹ́ ẹ sinu iboji titun ti on tikararẹ̀, eyi ti a gbẹ ninu apata: o si yi okuta nla di ẹnu-ọ̀na ibojì na, o si lọ.
Pín
Mat 27YBCVMat 27:60BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì tẹ́ ẹ sínú ibojì òkúta tí ó gbẹ́ nínú àpáta fúnra rẹ̀. Ó sì yí òkúta ńlá dí ẹnu-ọ̀nà ibojì náà, ó sì lọ.
Pín
Mat 27BMYOMat 27:60YCE(Yoruba Bible)
Ó tẹ́ ẹ sí inú ibojì rẹ̀ titun tí òun tìkalárarẹ̀ ti gbẹ́ sí inú àpáta. Ó yí òkúta ńlá kan dí ẹnu ọ̀nà ibojì náà. Ó bá kúrò níbẹ̀.
Pín
Mat 27YCE