Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 27:59YBCV(Bibeli Mimọ)

Josefu si gbé okú na, o si fi aṣọ ọ̀gbọ mimọ́ dì i

Mat 27:59BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Josẹfu sì gbé òkú náà. Ó fi aṣọ funfun mímọ́ dì í.

Mat 27:59YCE(Yoruba Bible)

Nígbà tí Josẹfu ti gba òkú náà, ó fi aṣọ funfun tí ó mọ́ wé e.