Mat 27:56 - Compare All Versions

Mat 27:56 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ninu awọn ẹniti Maria Magdalene wà, ati Maria iya Jakọbu ati Jose, ati iya awọn ọmọ Sebede.

Mat 27:56 YCE (Yoruba Bible)

Maria Magidaleni wà lára wọn, ati Maria ìyá Jakọbu ati ti Josẹfu ati ìyá àwọn ọmọ Sebede.

Mat 27:56 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nínú àwọn obìnrin ti ó wà níbẹ̀ ni Maria Magdalene, àti Maria ìyá Jakọbu àti Josẹfu, àti ìyá àwọn ọmọ Sebede méjèèjì wà níbẹ̀ pẹ̀lú.