Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 27:51YBCV(Bibeli Mimọ)

Si wo o, aṣọ ikele tẹmpili si ya si meji lati oke de isalẹ; ilẹ si mì titi, awọn apata si sán

Mat 27:51BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Lójúkan náà aṣọ ìkélé tẹmpili fàya, láti òkè dé ìsàlẹ̀. Ilẹ̀ sì mì tìtì. Àwọn àpáta sì sán.

Mat 27:51YCE(Yoruba Bible)

Aṣọ ìkélé tí ó wà ninu Tẹmpili ya sí meji láti òkè dé ilẹ̀. Ilẹ̀ mì tìtì. Àwọn òkè sán.