Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 27:4YBCV(Bibeli Mimọ)
O wipe, emi ṣẹ̀ li eyiti mo fi ẹ̀jẹ alaiṣẹ̀ hàn. Nwọn si wipe, Kò kàn wa, mã bojuto o.
Pín
Mat 27YBCVMat 27:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wí pé, “Mo ti ṣẹ̀ nítorí tí mo ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìlẹ́ṣẹ̀ sílẹ̀.” Wọ́n dá a lóhùn pẹ̀lú ìbínú pé, “Èyí kò kàn wá! Wàhálà tìrẹ ni!”
Pín
Mat 27BMYOMat 27:4YCE(Yoruba Bible)
Ó ní, “Mo ṣẹ̀ ní ti pé mo ṣe ikú pa aláìṣẹ̀.” Wọ́n bá dá a lóhùn pé, “Èwo ló kàn wá ninu rẹ̀? Ẹjọ́ tìrẹ ni.”
Pín
Mat 27YCE