Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 27:39YBCV(Bibeli Mimọ)

Awọn ti nkọja lọ si nfi ṣe ẹlẹyà, nwọn si nmì ori wọn

Mat 27:39BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àwọn tí ń kọjá lọ sì ń bú u. Wọ́n sì ń mi orí wọn pé

Mat 27:39YCE(Yoruba Bible)

Àwọn tí ó ń kọjá lọ ń sọ ìsọkúsọ sí i. Wọ́n ń já apá mọ́nú