Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 27:16YBCV(Bibeli Mimọ)

Nwọn si ni ondè buburu kan lakoko na, ti a npè ni Barabba.

Mat 27:16BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ní àsìkò náà ọ̀daràn paraku kan wà nínú ẹ̀wọ̀n tí à ń pè Jesu Baraba.

Mat 27:16YCE(Yoruba Bible)

Ní àkókó náà, ẹlẹ́wọ̀n olókìkí kan wà tí ó ń jẹ́ Jesu Baraba.