Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 26:9YBCV(Bibeli Mimọ)
A ba sá tà ikunra yi ni owo iyebiye, a ba si fifun awọn talakà.
Pín
Mat 26YBCVMat 26:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èéha ti ṣe, obìnrin yìí ìbá tà á ní owó púpọ̀, kí a sì fi owó náà fún àwọn aláìní.”
Pín
Mat 26BMYOMat 26:9YCE(Yoruba Bible)
Nítorí títà ni à bá ta òróró yìí ní owó iyebíye tí à bá fi fún àwọn talaka.”
Pín
Mat 26YCE