Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 26:61YBCV(Bibeli Mimọ)
Nwọn wipe, ọkunrin yi wipe, Emi le wó tẹmpili Ọlọrun, emi o si kọ́ ọ ni ijọ mẹta.
Pín
Mat 26YBCVMat 26:61BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn wí pé, “Ọkùnrin yìí sọ pé, ‘Èmi lágbára láti wó tẹmpili Ọlọ́run lulẹ̀, èmi yóò sì tún un mọ ní ọjọ́ mẹ́ta.’ ”
Pín
Mat 26BMYOMat 26:61YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n ní, “Ọkunrin yìí sọ pé, ‘Mo lè wó Tẹmpili Ọlọrun yìí, kí n sì tún un kọ́ ní ọjọ́ mẹta.’ ”
Pín
Mat 26YCE