Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 26:6YBCV(Bibeli Mimọ)

Nigbati Jesu si wà ni Betani ni ile Simoni adẹtẹ̀

Mat 26:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nígbà tí Jesu wà ní Betani ní ilé ọkùnrin tí à ń pè ní Simoni adẹ́tẹ̀.

Mat 26:6YCE(Yoruba Bible)

Nígbà tí Jesu wà ní Bẹtani, ninu ilé Simoni tí ó dẹ́tẹ̀ nígbà kan rí