Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 26:51YBCV(Bibeli Mimọ)
Si wo o, ọkan ninu awọn ti o wà pẹlu Jesu nà ọwọ́ rẹ̀, o si fà idà rẹ̀ yọ, o si ṣá ọkan ti iṣe ọmọ-ọdọ olori alufa, o si ke e li etí sọnù.
Pín
Mat 26YBCVMat 26:51BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sì wò ó, ọ̀kan nínú àwọn tí ó wà pẹ̀lú Jesu na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fa idà yọ, ó sì sá ọ̀kan tí i ṣe ọmọ ọ̀dọ̀ olórí àlùfáà, ó sì gé e ní etí sọnù.
Pín
Mat 26BMYOMat 26:51YCE(Yoruba Bible)
Ọ̀kan ninu àwọn tí ó wà pẹlu Jesu bá na ọwọ́, ó fa idà yọ, ó sì fi ṣá ẹrú Olórí Alufaa kan, ó gé e létí.
Pín
Mat 26YCE