Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 26:21YBCV(Bibeli Mimọ)
Bi nwọn si ti njẹun, o wipe, Lõtọ, ni mo wi fun nyin, ọkan ninu nyin yio fi mi hàn.
Pín
Mat 26YBCVMat 26:21BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
nígbà tí wọ́n sì ń jẹun, ó wí pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀kan nínú yín yóò fi mí hàn.”
Pín
Mat 26BMYOMat 26:21YCE(Yoruba Bible)
Bí wọ́n ti ń jẹun, ó wí fún wọn pé, “Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé ọ̀kan ninu yín yóo fi mí fún àwọn ọ̀tá.”
Pín
Mat 26YCE