Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 26:14YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana li ọkan ninu awọn mejila, ti a npè ni Judasi Iskariotu tọ̀ awọn olori alufa lọ
Pín
Mat 26YBCVMat 26:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ọ̀kan nínú àwọn aposteli méjìlá ti à ń pè ní Judasi Iskariotu lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà.
Pín
Mat 26BMYOMat 26:14YCE(Yoruba Bible)
Nígbà náà ni ọ̀kan ninu àwọn mejila, tí ó ń jẹ́ Judasi Iskariotu, jáde lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí alufaa.
Pín
Mat 26YCE