Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 26:10YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati Jesu mọ̀, o wi fun wọn pe, Ẽṣe ti ẹnyin fi mba obinrin na wi? nitori iṣẹ rere li o ṣe si mi lara.
Pín
Mat 26YBCVMat 26:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jesu ti mọ èrò ọkàn wọn, ó wí pé, “Èéṣe ti ẹ̀yin fi ń dá obìnrin yìí lẹ́bi? Ó ṣe ohun tí ó dára fún mi.
Pín
Mat 26BMYOMat 26:10YCE(Yoruba Bible)
Jesu mọ ohun tí wọn ń sọ, nítorí náà, ó wí fún wọn pé, “Kí ni ẹ̀ ń da obinrin yìí láàmú sí? Nítorí iṣẹ́ rere ni ó ṣe sí mi lára.
Pín
Mat 26YCE