Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 25:7YBCV(Bibeli Mimọ)

Nigbana ni gbogbo awọn wundia wọnni dide, nwọn, si tún fitila wọn ṣe.

Mat 25:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

“Nígbà náà ni àwọn wúńdíá sì tají, wọ́n tún fìtílà wọn ṣe.

Mat 25:7YCE(Yoruba Bible)

Nígbà náà ni gbogbo àwọn wundia náà tají, wọ́n tún iná àtùpà wọn ṣe.