Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 25:28YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitorina ẹ gbà talenti na li ọwọ́ rẹ̀, ẹ si fifun ẹniti o ni talenti mẹwa.
Pín
Mat 25YBCVMat 25:28BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Ó sì pàṣẹ kí a gba tálẹ́ǹtì náà lọ́wọ́ rẹ̀, kí a sì fún ọkùnrin tí ó ní tálẹ́ǹtì mẹ́wàá.
Pín
Mat 25BMYOMat 25:28YCE(Yoruba Bible)
Nítorí náà, ẹ gba àpò kan náà lọ́wọ́ rẹ̀, kí ẹ fún ẹni tí ó ní àpò mẹ́wàá.
Pín
Mat 25YCE