Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 24:19YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn egbé ni fun awọn ti o lóyun, ati fun awọn ti o nfi ọmú fun ọmọ mu ni ijọ wọnni!
Pín
Mat 24YBCVMat 24:19BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àánú ṣe mí fún àwọn obìnrin ti ó lóyún, àti fún àwọn tí ó ń fún ọmọ loyan ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì!
Pín
Mat 24BMYOMat 24:19YCE(Yoruba Bible)
Ó ṣe! Fún àwọn aboyún ati fún àwọn tí wọn bá ń tọ́ ọmọ lọ́wọ́ ní ọjọ́ náà.
Pín
Mat 24YCE