Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 24:10YBCV(Bibeli Mimọ)

Nigbana li ọ̀pọlọpọ yio kọsẹ̀, nwọn o si ma ṣòfofo ara wọn, nwọn o si mã korira ara wọn.

Mat 24:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àti pé, ọ̀pọ̀ nínú yín yóò kọsẹ̀, ẹ̀yin yóò ṣòfófó ara yín, ẹ̀yin yóò kórìíra ara yín pẹ̀lú

Mat 24:10YCE(Yoruba Bible)

Ọpọlọpọ yóo kùnà ninu igbagbọ; wọn yóo tú àwọn mìíràn fó; wọn yóo sì kórìíra àwọn mìíràn.