Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 23:31YBCV(Bibeli Mimọ)
Njẹ ẹnyin li ẹlẹri fun ara nyin pe, ẹnyin li awọn ọmọ awọn ẹniti o pa awọn wolĩ.
Pín
Mat 23YBCVMat 23:31BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí fún ara yín pé, ẹ̀yin ni ọmọ àwọn tí ó pa àwọn wòlíì.
Pín
Mat 23BMYOMat 23:31YCE(Yoruba Bible)
Nípa gbolohun yìí, ẹ̀ ń jẹ́rìí sí ara yín pé ọmọ àwọn tí ó pa àwọn wolii ni yín.
Pín
Mat 23YCE