Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 23:26YBCV(Bibeli Mimọ)
Iwọ afọju Farisi, tetekọ fọ̀ eyi ti mbẹ ninu ago ati awopọkọ́ mọ́ na, ki ode wọn ki o le mọ́ pẹlu.
Pín
Mat 23YBCVMat 23:26BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ afọ́jú Farisi, tètè kọ́ fọ inú ago àti àwo, gbogbo ago náà yóò sì di mímọ́.
Pín
Mat 23BMYOMat 23:26YCE(Yoruba Bible)
Ìwọ afọ́jú Farisi! Kọ́kọ́ fọ inú ife ná, òde rẹ̀ náà yóo sì mọ́.
Pín
Mat 23YCE