Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 22:36YBCV(Bibeli Mimọ)

Olukọni, ewo li aṣẹ nla ninu ofin?

Mat 22:36BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ó wí pé, “Olùkọ́ èwo ni ó ga jùlọ nínú àwọn òfin?”

Mat 22:36YCE(Yoruba Bible)

“Olùkọ́ni, òfin wo ni ó ṣe pataki jùlọ ninu Ìwé Òfin?”