Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 22:34YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati awọn Farisi gbọ́ pe, o pa awọn Sadusi li ẹnu mọ́, nwọn pè ara wọn jọ.
Pín
Mat 22YBCVMat 22:34BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà ti wọ́n sì gbọ́ pé ó ti pa àwọn Sadusi lẹ́nu mọ́, àwọn Farisi pé ara wọn jọ.
Pín
Mat 22BMYOMat 22:34YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí àwọn Farisi gbọ́ pé ó ti pa àwọn Sadusi lẹ́nu mọ́, wọ́n kó ara wọn jọ.
Pín
Mat 22YCE