Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 22:31YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn niti ajinde okú, ẹnyin kò ti kà eyi ti a sọ fun nyin lati ọdọ Ọlọrun wá wipe
Pín
Mat 22YBCVMat 22:31BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, nípa ti àjíǹde òkú, tàbí ẹ̀yin kò mọ̀ pé Ọlọ́run ń bá yín sọ̀rọ̀ nígbà ti ó wí pé
Pín
Mat 22BMYOMat 22:31YCE(Yoruba Bible)
Nípa ti ajinde àwọn òkú, ẹ kò ì tíì ka ọ̀rọ̀ tí Ọlọrun sọ fun yín pé
Pín
Mat 22YCE