Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 22:26YBCV(Bibeli Mimọ)

Gẹgẹ bẹ̃li ekeji pẹlu, ati ẹkẹta titi o fi de ekeje.

Mat 22:26BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ arákùnrin èkejì náà sì tún kú láìlọ́mọ. A sì fi ìyàwó rẹ̀ fún arákùnrin tí ó tún tẹ̀lé e. Bẹ́ẹ̀ sì ni títí tí òun fi di ìyàwó ẹni keje.

Mat 22:26YCE(Yoruba Bible)

Ekeji náà kú, ati ẹkẹta, títí tí àwọn mejeeje fi kú.