Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 22:17YBCV(Bibeli Mimọ)
Njẹ wi fun wa, Iwọ ti rò o si? Ó tọ́ lati mã san owode fun Kesari, tabi ko tọ́?
Pín
Mat 22YBCVMat 22:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nísinsin yìí sọ fún wa, kí ni èrò rẹ? Ǹjẹ́ ó tọ́ láti san owó orí fún Kesari tàbí kò tọ́?”
Pín
Mat 22BMYOMat 22:17YCE(Yoruba Bible)
Nítorí náà sọ ohun tí o rò fún wa. Ó tọ̀nà láti san owó-orí fún Kesari ni, àbí kò tọ̀nà?”
Pín
Mat 22YCE