Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 22:15YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana li awọn Farisi lọ, nwọn gbìmọ bi nwọn o ti ṣe ri ọ̀rọ gbámọ ọ li ẹnu.
Pín
Mat 22YBCVMat 22:15BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni àwọn Farisi péjọpọ̀ láti ronú ọ̀nà tì wọn yóò gbà fi ọ̀rọ̀ ẹnu mú un.
Pín
Mat 22BMYOMat 22:15YCE(Yoruba Bible)
Àwọn Farisi bá lọ forí-korí wọ́n ń wá ọ̀nà tí wọn yóo fi ká ọ̀rọ̀ mọ́ Jesu lẹ́nu.
Pín
Mat 22YCE