Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 20:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn ti a pè lakokò wakati kọkanla ọjọ de, gbogbo wọn gbà owo idẹ kọkan.
Pín
Mat 20YBCVMat 20:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà tí àwọn ti a pè ní wákàtí kọkànlá ọjọ́ dé, ẹnìkọ̀ọ̀kan gba owó dínárì kan.
Pín
Mat 20BMYOMat 20:9YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí àwọn tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní agogo marun-un ìrọ̀lẹ́ dé, wọ́n gba owó fadaka kọ̀ọ̀kan.
Pín
Mat 20YCE