Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 20:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati o si ba awọn alagbaṣe pinnu rẹ̀ si owo idẹ kọkan li õjọ, o rán wọn lọ sinu ọgba ajara rẹ̀.
Pín
Mat 20YBCVMat 20:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun pinnu láti san dínárì kan fún iṣẹ́ òòjọ́ kan. Lẹ́yìn èyí ó sì rán wọn lọ sínú ọgbà àjàrà rẹ̀.
Pín
Mat 20BMYOMat 20:2YCE(Yoruba Bible)
Lẹ́yìn tí ó ti gbà láti fún àwọn òṣìṣẹ́ náà ní owó fadaka kan fún iṣẹ́ ojúmọ́, ó ní kí wọ́n lọ ṣiṣẹ́ ninu ọgbà àjàrà òun.
Pín
Mat 20YCE