Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 20:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Wipe, Awọn ará ikẹhin wọnyi ṣiṣẹ kìki wakati kan, iwọ si mu wọn bá wa dọgba, awa ti o ti rù ẹrù, ti a si faradà õru ọjọ.
Pín
Mat 20YBCVMat 20:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
pé, ‘Wákàtí kan péré ni àwọn tí a gbà kẹ́yìn fi ṣiṣẹ́, ìwọ sì san iye kan náà fún wọn àti àwa náà ti a fi gbogbo ọjọ́ ṣiṣẹ́ nínú oòrùn gangan.’
Pín
Mat 20BMYOMat 20:12YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n ní, ‘Wakati kan péré ni àwọn yìí tí wọ́n dé kẹ́yìn ṣe; o wá san iye kan náà fún àwa ati àwọn, àwa tí a ṣe iṣẹ́ àṣelàágùn ninu oòrùn gangan!’
Pín
Mat 20YCE