Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 2:14YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati o si dide, o mu ọmọ-ọwọ na ati iya rẹ̀ li oru, o si lọ si Egipti
Pín
Mat 2YBCVMat 2:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ó sì dìde, ó mú ọmọ ọwọ́ náà àti ìyá rẹ̀ ní òru, ó sì lọ sí Ejibiti
Pín
Mat 2BMYOMat 2:14YCE(Yoruba Bible)
Josẹfu bá dìde ní òru, ó gbé ọmọ náà ati ìyá rẹ̀, ó lọ sí Ijipti.
Pín
Mat 2YCE