Mat 19:6
Mat 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Wọn kì í túnṣe méjì mọ́, ṣùgbọ́n ara kan. Nítorí náà, ohun tí Ọlọ́run bá ti so ṣọ̀kan, kí ẹnikẹ́ni má ṣe yà wọ́n.”
Pín
Kà Mat 19Mat 19:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitorina nwọn ki iṣe meji mọ́ bikoṣe ara kan. Nitorina ohun ti Ọlọrun ba so ṣọkan, ki enia ki o máṣe yà wọn.
Pín
Kà Mat 19