Mat 19:22
Mat 19:22 Yoruba Bible (YCE)
Nígbà tí ọdọmọkunrin náà gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ó kúrò níbẹ̀ pẹlu ìbànújẹ́ nítorí ó ní ọrọ̀ pupọ.
Pín
Kà Mat 19Mat 19:22 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn nigbati ọmọdekunrin na gbọ́ ọ̀rọ na, o jade lọ pẹlu ibanujẹ: nitoriti o li ọrọ̀ pupọ̀.
Pín
Kà Mat 19