Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 19:15YBCV(Bibeli Mimọ)

O si fi ọwọ́ le wọn, o si lọ kuro nibẹ̀.

Mat 19:15BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Lẹ́yìn náà, ó gbé ọwọ́ lé wọn, ó sì kúrò níbẹ̀.

Mat 19:15YCE(Yoruba Bible)

Ó bá gbé ọwọ́ lé wọn; ó sì kúrò níbẹ̀.