Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 18:34YBCV(Bibeli Mimọ)
Oluwa rẹ̀ si binu, o fi i fun awọn onitubu, titi yio fi san gbogbo gbese eyi ti o jẹ ẹ.
Pín
Mat 18YBCVMat 18:34BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìbínú, olówó rẹ̀ fi í lé àwọn onítúbú lọ́wọ́ láti fi ìyà jẹ ẹ́, títí tí yóò fi san gbogbo gbèsè èyí ti ó jẹ ẹ́.
Pín
Mat 18BMYOMat 18:34YCE(Yoruba Bible)
Inú bí olówó rẹ̀, ó bá fà á fún ọ̀gá àwọn ẹlẹ́wọ̀n pé kí wọ́n sọ ọ́ sẹ́wọ̀n títí yóo fi san gbogbo gbèsè tí ó jẹ tán.
Pín
Mat 18YCE