Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 18:17YBCV(Bibeli Mimọ)
Bi o ba si kọ̀ lati gbọ́ wọn, wi fun ijọ enia Ọlọrun: bi o ba si kọ̀ lati gbọ́ ti ijọ enia Ọlọrun, jẹ ki o dabi keferi si ọ ati agbowodè.
Pín
Mat 18YBCVMat 18:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí òun bá sì tún kọ̀ láti tẹ́tí sí wọn, nígbà náà sọ fún ìjọ ènìyàn Ọlọ́run. Bí o bá kọ̀ láti gbọ́ ti ìjọ ènìyàn Ọlọ́run, jẹ́ kí ó dàbí kèfèrí sí ọ tàbí agbowó òde.
Pín
Mat 18BMYOMat 18:17YCE(Yoruba Bible)
Bí kò bá gba tiwọn, sọ fún ìjọ. Bí kò bá gba ti ìjọ, kà á kún alaigbagbọ tabi agbowó-odè.
Pín
Mat 18YCE