Mat 16:15-16
Mat 16:15-16 Yoruba Bible (YCE)
Ó wá bi wọ́n pé, “Ẹ̀yin ńkọ́? Ta ni ẹ rò pé mo jẹ́?” Simoni Peteru dá a lóhùn pé, “Ìwọ ni Mesaya, Ọmọ Ọlọrun Alààyè.”
Pín
Kà Mat 16Mat 16:15-16 Bibeli Mimọ (YBCV)
O bi wọn lẽre, wipe, Ṣugbọn tali ẹnyin nfi mi pè? Simoni Peteru dahùn, wipe, Kristi, Ọmọ Ọlọrun alãye ni iwọ iṣe.
Pín
Kà Mat 16