Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 15:8YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn enia yi nfi ẹnu wọn sunmọ mi, nwọn si nfi ète wọn bọla fun mi; ṣugbọn ọkàn wọn jìna si mi.
Pín
Mat 15YBCVMat 15:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Àwọn ènìyàn wọ̀nyí ń fi ẹnu lásán bu ọlá fún mi, ṣùgbọ́n ọkàn wọn jìnnà réré sí mi.
Pín
Mat 15BMYOMat 15:8YCE(Yoruba Bible)
‘Ọlọrun sọ pé: Ẹnu lásán ni àwọn eniyan wọnyi fi ń bọlá fún mi, ọkàn wọn jìnnà pupọ sí mi.
Pín
Mat 15YCE