Mat 15:10-11
Mat 15:10-11 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si pè ijọ enia, o si wi fun wọn pe, Ẹ gbọ́ ki o si ye nyin; Ki iṣe ohun ti o wọni li ẹnu lọ, ni isọ enia di alaimọ́; bikoṣe eyi ti o ti ẹnu jade wá, eyini ni isọ enia di alaimọ́.
Pín
Kà Mat 15