Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 14:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitorina li o ṣe fi ibura ṣe ileri lati fun u li ohunkohun ti o ba bère.
Pín
Mat 14YBCVMat 14:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni ó ṣe fi ìbúra ṣe ìlérí láti fún un ní ohunkóhun ti ó bá béèrè fún.
Pín
Mat 14BMYOMat 14:7YCE(Yoruba Bible)
tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi fi ìbúra ṣe ìlérí láti fún un ní ohunkohun tí ó bá bèèrè.
Pín
Mat 14YCE