Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 14:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn nigbati a nṣe iranti ọjọ ibí Herodu, ọmọbinrin Herodia jó lãrin wọn, inu Herodu si dùn.
Pín
Mat 14YBCVMat 14:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ àsè ìrántí ọjọ́ ìbí Herodu, ọmọ Herodia obìnrin jó dáradára, ó sì tẹ́ Herodu lọ́run gidigidi.
Pín
Mat 14BMYOMat 14:6YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí Hẹrọdu ń ṣe ọjọ́ ìbí rẹ̀, ọdọmọbinrin Hẹrọdiasi bẹ̀rẹ̀ sí jó lójú agbo. Èyí dùn mọ́ Hẹrọdu ninu
Pín
Mat 14YCE