Mat 14:25
Mat 14:25 Yoruba Bible (YCE)
Nígbà tí ó di nǹkan bí agogo mẹta òru, Jesu ń bọ̀ lọ́dọ̀ wọn, ó ń rìn lójú omi òkun.
Pín
Kà Mat 14Mat 14:25 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbati o di iṣọ kẹrin oru, Jesu tọ̀ wọn lọ, o nrìn lori okun.
Pín
Kà Mat 14