Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Mat 14:10YBCV(Bibeli Mimọ)

O si ranṣẹ lọ, o bẹ́ Johanu li ori ninu tubu.

Mat 14:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí náà, a bẹ́ orí Johanu onítẹ̀bọmi nínú ilé túbú.

Mat 14:10YCE(Yoruba Bible)

Ọba bá ranṣẹ pé kí wọ́n bẹ́ Johanu lórí ninu ẹ̀wọ̀n tí ó wá.