Mat 13:46
Mat 13:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nígbà tí ó rí ọ̀kan tí ó ni iye lórí, ó lọ láti ta gbogbo ohun ìní rẹ̀ láti le rà á.
Pín
Kà Mat 13Mat 13:46 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbati o ri perli olowo iyebiye kan, o lọ, o si tà gbogbo nkan ti o ni, o si rà á.
Pín
Kà Mat 13