Mat 13:39
Mat 13:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
ọ̀tá tí ó gbin àwọn èpò sáàrín alikama ni èṣù. Ìkórè ni òpin ayé, àwọn olùkórè sì ní àwọn angẹli.
Pín
Kà Mat 13Mat 13:39 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọta ti o fún wọn li Èṣu; igbẹhin aiye ni ikorè; awọn angẹli si li awọn olukore.
Pín
Kà Mat 13