Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 13:24YBCV(Bibeli Mimọ)
Owe miran li o pa fun wọn, wipe: Ijọba ọrun dabi ọkunrin ti o fún irugbin rere si oko rẹ̀
Pín
Mat 13YBCVMat 13:24BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jesu tún pa òwe mìíràn fún wọn: “Ìjọba ọ̀run dàbí àgbẹ̀ kan tí ó gbin irúgbìn rere sí oko rẹ̀
Pín
Mat 13BMYOMat 13:24YCE(Yoruba Bible)
Ó tún pa òwe mìíràn fún wọn. Ó ní, “Bí ìjọba ọ̀run ti rí nìyí. Ó dàbí ọkunrin kan tí ó gbin irúgbìn rere sí oko rẹ̀.
Pín
Mat 13YCE