Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 12:49YBCV(Bibeli Mimọ)
O si nà ọwọ́ rẹ̀ si awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, o wipe, Ẹ wò iya mi ati awọn arakunrin mi!
Pín
Mat 12YBCVMat 12:49BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó nawọ́ sí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí pé, “Wò ó, ìyá mi àti àwọn arákùnrin mi ni wọ̀nyí.”
Pín
Mat 12BMYOMat 12:49YCE(Yoruba Bible)
Ó bá nawọ́ sí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó ní, “Wò ó ìyá mi ati àwọn arakunrin mi nìwọ̀nyí.
Pín
Mat 12YCE