Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 12:39YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn o dahùn o si wi fun wọn pe, Iran buburu ati iran panṣaga nwá àmi; kò si àmi ti a o fi fun u, bikoṣe àmi Jona wolĩ.
Pín
Mat 12YBCVMat 12:39BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì dá wọn lóhùn wí pé, “Ìran búburú àti ìran panṣágà ń béèrè àmì; ṣùgbọ́n kò sí àmì tí a ó fi fún un, bí kò ṣe àmì Jona wòlíì.
Pín
Mat 12BMYOMat 12:39YCE(Yoruba Bible)
Ṣugbọn Jesu dá wọn lóhùn pé, “Ìran burúkú ati ìran oníbọkúbọ ń wá àmì. Kò sí àmì kan tí a óo fi fún un àfi àmì Jona wolii.
Pín
Mat 12YCE