Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 12:3YBCV(Bibeli Mimọ)
O si wi fun wọn pe, Ẹnyin kò ti kà ohun ti Dafidi ṣe, nigbati ebi npa a, ati awọn ti mbẹ lọdọ rẹ̀
Pín
Mat 12YBCVMat 12:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jesu dáhùn pé, “Ẹ̀yin kò ha ka ohun tí Dafidi ṣe nígbà tí ebi ń pa á àti àwọn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀.
Pín
Mat 12BMYOMat 12:3YCE(Yoruba Bible)
Ṣugbọn Jesu dá wọn lóhùn pé, “Ẹ kò kà nípa ohun tí Dafidi ṣe nígbà tí ebi ń pa òun ati àwọn tí ó wà pẹlu rẹ̀?
Pín
Mat 12YCE