Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Mat 12:29YBCV(Bibeli Mimọ)
Tabi ẹnikan yio ti ṣe wọ̀ ile alagbara lọ, ki o si kó o li ẹrù, bikoṣepe o kọ́ dè alagbara na? nigbana ni yio si kó o ni ile.
Pín
Mat 12YBCVMat 12:29BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Tàbí, báwo ni ẹnikẹ́ni ṣe lè wọ ilé alágbára lọ kí ó sì kó ẹrù rẹ̀, bí kò ṣe pé ó kọ́kọ́ di alágbára náà? Nígbà náà ni ó tó lè kó ẹrù rẹ̀ lọ.
Pín
Mat 12BMYOMat 12:29YCE(Yoruba Bible)
“Báwo ni ẹnìkan ṣe lè wọ ilé alágbára lọ, kí ó kó o lẹ́rù, bí kò bá kọ́kọ́ de alágbára náà? Bí ó bá kọ́kọ́ dè é ni yóo tó lè kó o lẹ́rù.
Pín
Mat 12YCE